Samuẹli Keji 10:16 BM

16 Hadadeseri ọba, bá ranṣẹ sí àwọn ará Siria tí wọ́n wà ní ìhà ìlà oòrùn odò Yufurate, wọ́n bá wá sí Helamu. Ṣobaki tí ó jẹ́ balogun àwọn ọmọ ogun Hadadeseri, ni aṣiwaju wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 10

Wo Samuẹli Keji 10:16 ni o tọ