16 Nítorí náà, nígbà tí Joabu dóti ìlú Raba, ó rán Uraya lọ sí ibi tí ó mọ̀ pé àwọn ọ̀tá ti lágbára gidigidi.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 11
Wo Samuẹli Keji 11:16 ni o tọ