Samuẹli Keji 11:17 BM

17 Àwọn ọmọ ogun àwọn ọ̀tá jáde láti inú ìlú láti bá àwọn ọmọ ogun Joabu jà. Wọ́n pa ninu àwọn ọ̀gágun Dafidi, wọ́n sì pa Uraya ará Hiti náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 11

Wo Samuẹli Keji 11:17 ni o tọ