Samuẹli Keji 13:10 BM

10 Amnoni bá sọ fún un pé, “Gbé e tọ̀ mí wá ninu yàrá mi, kí o sì gbé e kalẹ̀ níwájú mi.” Tamari bá gbé àkàrà náà, ó sì tọ Amnoni lọ láti gbé e kalẹ̀ níwájú rẹ̀ ninu yàrá.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13

Wo Samuẹli Keji 13:10 ni o tọ