Samuẹli Keji 13:9 BM

9 ó sì dà á sinu àwo kan, ó gbé e fún un. Ṣugbọn Amnoni kọ̀, kò jẹ ẹ́, ó ní kí ó sọ fún gbogbo àwọn tí wọ́n wà ninu ilé kí wọ́n jáde, gbogbo wọn bá jáde.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13

Wo Samuẹli Keji 13:9 ni o tọ