Samuẹli Keji 13:16 BM

16 Tamari dá a lóhùn pé, “Rárá, arakunrin mi, lílé tí ò ń lé mi jáde yìí burú ju ipá tí o fi bá mi lòpọ̀ lọ.”Ṣugbọn Amnoni kọ̀, kò gbọ́ tirẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13

Wo Samuẹli Keji 13:16 ni o tọ