17 Kàkà bẹ́ẹ̀, Amnoni pe iranṣẹ rẹ̀ kan, ó wí fún un pé, “Mú obinrin yìí jáde kúrò níwájú mi, tì í sóde, kí o sì ti ìlẹ̀kùn mọ́ ọn.”
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13
Wo Samuẹli Keji 13:17 ni o tọ