Samuẹli Keji 13:25 BM

25 Ọba ní, “Rárá, ọmọ mi, bí gbogbo wa bá lọ, wahala náà yóo pọ̀jù fún ọ.” Absalomu rọ ọba títí, ṣugbọn ó kọ̀ jálẹ̀. Ọba bá súre fún un, ó ní kí ó máa lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13

Wo Samuẹli Keji 13:25 ni o tọ