26 Absalomu dáhùn pé, “Ó dára, bí o kò bá lè lọ, ṣé o óo jẹ́ kí Amnoni arakunrin mi lọ?”Ọba bá bèèrè pé, “Nítorí kí ni yóo ṣe ba yín lọ?”
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 13
Wo Samuẹli Keji 13:26 ni o tọ