Samuẹli Keji 18:1 BM

1 Dafidi kó gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ jọ, ó pín wọn ní ọgọọgọrun-un (100) ati ẹgbẹẹgbẹrun (1,000), ó fi balogun kọ̀ọ̀kan ṣe olórí ìsọ̀rí kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18

Wo Samuẹli Keji 18:1 ni o tọ