Samuẹli Keji 18:2 BM

2 Lẹ́yìn náà, ó rán wọn jáde ní ìpín mẹta, ó fi Joabu, ati Abiṣai, ọmọ Seruaya, àbúrò Joabu, ati Itai, ará Gati, ṣe ọ̀gágun àgbà ìpín kọ̀ọ̀kan. Ó ní òun pàápàá yóo bá wọn lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 18

Wo Samuẹli Keji 18:2 ni o tọ