Samuẹli Keji 2:29 BM

29 Gbogbo òru ọjọ́ náà ni Abineri ati àwọn eniyan rẹ̀ fi ń rìn pada lọ ní àfonífojì Jọdani, wọ́n kọjá sí òdìkejì odò Jọdani. Gbogbo òwúrọ̀ ọjọ́ keji ni wọ́n sì fi rìn kí wọ́n tó pada dé Mahanaimu.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:29 ni o tọ