Samuẹli Keji 2:30 BM

30 Nígbà tí Joabu pada lẹ́yìn Abineri, tí ó sì kó gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ jọ, ó rí i pé, lẹ́yìn Asaheli, àwọn mejidinlogun ni wọn kò rí mọ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 2

Wo Samuẹli Keji 2:30 ni o tọ