Samuẹli Keji 20:4 BM

4 Lẹ́yìn náà, ọba sọ fún Amasa pé, “Pe gbogbo àwọn ọkunrin Juda jọ, kí o sì kó wọn wá sọ́dọ̀ mi láàrin ọjọ́ mẹta; kí ìwọ náà sì wá.”

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 20

Wo Samuẹli Keji 20:4 ni o tọ