Samuẹli Keji 21:15 BM

15 Ogun mìíràn tún bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ará Filistia ati àwọn ọmọ Israẹli. Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ sì lọ bá àwọn ará Filistia jagun. Bí wọ́n ti ń jà, àárẹ̀ mú Dafidi.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:15 ni o tọ