Samuẹli Keji 21:16 BM

16 Òmìrán kan tí ń jẹ́ Iṣibibenobu, gbèrò láti pa Dafidi. Ọ̀kọ̀ Iṣibibenobu yìí wọ̀n tó ọọdunrun ṣekeli idẹ, ó sì so idà tuntun mọ́ ẹ̀gbẹ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:16 ni o tọ