Samuẹli Keji 21:22 BM

22 Láti ìran àwọn òmìrán ìlú Gati ni àwọn mẹrẹẹrin ti wá, Dafidi ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ni ó sì pa wọ́n.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 21

Wo Samuẹli Keji 21:22 ni o tọ