Samuẹli Keji 22:1 BM

1 Nígbà tí OLUWA gba Dafidi lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ ati lọ́wọ́ Saulu, Dafidi kọ orin yìí sí OLUWA pé:

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 22

Wo Samuẹli Keji 22:1 ni o tọ