Samuẹli Keji 23:6 BM

6 Ṣugbọn àwọn tí wọn kò mọ Ọlọrundàbí igi ẹ̀gún tí a gbé sọnù,kò sí ẹni tí ó lè fi ọwọ́ lásán gbá wọn mú.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 23

Wo Samuẹli Keji 23:6 ni o tọ