7 Inú bí OLUWA sí Usa, OLUWA sì lù ú pa nítorí pé ó fi ọwọ́ kan àpótí ẹ̀rí náà. Usa kú sẹ́gbẹ̀ẹ́ àpótí ẹ̀rí náà.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 6
Wo Samuẹli Keji 6:7 ni o tọ