8 Inú bí Dafidi gidigidi nítorí pé OLUWA lu Usa pa. Láti ìgbà náà ni wọ́n ti ń pe ibẹ̀ ní Peresi Usa, títí di òní olónìí.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 6
Wo Samuẹli Keji 6:8 ni o tọ