14 N óo jẹ́ baba fún un, yóo sì jẹ́ ọmọ mi. Bí ó bá ṣẹ̀, n óo bá a wí, n óo sì jẹ ẹ́ níyà, bí baba ti í ṣe sí ọmọ rẹ̀.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 7
Wo Samuẹli Keji 7:14 ni o tọ