15 Ṣugbọn n kò ní káwọ́ ìfẹ́ ńlá mi kúrò lára rẹ̀, bí mo ti ká a kúrò lára Saulu, tí mo sì yọ ọ́ lóyè, kí n tó fi í jọba.
Ka pipe ipin Samuẹli Keji 7
Wo Samuẹli Keji 7:15 ni o tọ