Matiu 20:14 BM

14 Gba ohun tí ó tọ́ sí ọ kí o máa bá tìrẹ lọ; nítorí ó wù mí láti fún àwọn yìí tí wọ́n dé kẹ́yìn yìí ní ohun tí mo fún ọ.

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:14 ni o tọ