Matiu 20:15 BM

15 Àbí n kò ní ẹ̀tọ́ láti ṣe ohun ìní mi bí mo ti fẹ́? Ṣé ò ń jowú nítorí mo ní inú rere ni?’

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:15 ni o tọ