Matiu 28:1 BM

1 Nígbà tí Ọjọ́ Ìsinmi ti kọjá, tí ilẹ̀ fẹ́rẹ̀ mọ́ ní ọjọ́ kinni ọ̀sẹ̀, Maria Magidaleni ati Maria keji wá wo ibojì Jesu.

Ka pipe ipin Matiu 28

Wo Matiu 28:1 ni o tọ