Matiu 28:2 BM

2 Ilẹ̀ mì tìtì, nítorí angẹli Oluwa sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run wá. Ó yí òkúta tí ó wà lẹ́nu ibojì kúrò, ó sì jókòó lórí rẹ̀.

Ka pipe ipin Matiu 28

Wo Matiu 28:2 ni o tọ