Matiu 28:10 BM

10 Jesu wá sọ fún wọn pé, “Ẹ má bẹ̀rù. Ẹ lọ sọ fún àwọn arakunrin mi pé kí wọ́n lọ sí Galili; níbẹ̀ ni wọn yóo ti rí mi.”

Ka pipe ipin Matiu 28

Wo Matiu 28:10 ni o tọ