Matiu 28:9 BM

9 Lójijì Jesu pàdé wọn, ó kí wọn, ó ní, “Ẹ pẹ̀lẹ́ o!” Wọ́n bá dì mọ́ ọn lẹ́sẹ̀, wọ́n júbà rẹ̀.

Ka pipe ipin Matiu 28

Wo Matiu 28:9 ni o tọ