Romu 10:1 BM

1 Ẹ̀yin ará mi, ìfẹ́ ọkàn mi, ati ẹ̀bẹ̀ mi sí Ọlọrun fún àwọn Juu, àwọn eniyan mi ni pé kí á gbà wọ́n là.

Ka pipe ipin Romu 10

Wo Romu 10:1 ni o tọ