Romu 10:2 BM

2 Nítorí mo jẹ́rìí wọn pé wọ́n ní ìtara láti sin Ọlọrun, ṣugbọn wọn kò ní òye bí ó ti yẹ kí wọ́n sìn ín.

Ka pipe ipin Romu 10

Wo Romu 10:2 ni o tọ