Romu 12:13 BM

13 Ẹ pín àwọn aláìní láàrin àwọn onigbagbọ ninu ohun ìní yín. Ẹ máa ṣaájò àwọn àlejò.

Ka pipe ipin Romu 12

Wo Romu 12:13 ni o tọ