Romu 12:14 BM

14 Ẹ máa súre fún àwọn tí ó ń ṣe inúnibíni yín, kàkà kí ẹ ṣépè, ìre ni kí ẹ máa sú fún wọn.

Ka pipe ipin Romu 12

Wo Romu 12:14 ni o tọ