Hos 11:5 YCE

5 On kì yio yipadà si ilẹ Egipti, ṣugbọn ara Assiria ni yio jẹ ọba rẹ̀, nitori nwọn kọ̀ lati yipadà.

Ka pipe ipin Hos 11

Wo Hos 11:5 ni o tọ