Hos 5:5 YCE

5 A si rẹ̀ ogo Israeli silẹ loju ara rẹ̀; nitorina ni Israeli ati Efraimu yio ṣubu ninu aiṣedẽde wọn, Juda yio si ṣubu pẹlu wọn.

Ka pipe ipin Hos 5

Wo Hos 5:5 ni o tọ