2. A. Ọba 10:22 YCE

22 On si wi fun ẹniti o wà lori yará babaloriṣa pe, Kó aṣọ wá fun gbogbo awọn olùsin Baali. On si kó aṣọ jade fun wọn wá.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 10

Wo 2. A. Ọba 10:22 ni o tọ