2. A. Ọba 10:34 YCE

34 Ati iyokù iṣe Jehu, ati gbogbo ohun ti o ṣe, ati gbogbo agbara rẹ̀, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Israeli?

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 10

Wo 2. A. Ọba 10:34 ni o tọ