2. A. Ọba 10:35 YCE

35 Jehu si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀: nwọn si sìn i ni Samaria. Jehoahasi ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 10

Wo 2. A. Ọba 10:35 ni o tọ