2. A. Ọba 12:5 YCE

5 Ẹ jẹ ki awọn alufa ki o mu u tọ̀ ara wọn, olukuluku lati ọwọ ojulùmọ rẹ̀: ẹ si jẹ ki nwọn ki o tun ẹya ile na ṣe, nibikibi ti a ba ri ẹya.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 12

Wo 2. A. Ọba 12:5 ni o tọ