2. A. Ọba 15:22 YCE

22 Menahemu si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀; Pekahiah ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 15

Wo 2. A. Ọba 15:22 ni o tọ