23 Ni ãdọta ọdun Asariah ọba Juda, Pekahiah ọmọ Menahemu bẹ̀rẹ si ijọba lori Israeli ni Samaria, o si jọba ọdun meji.
Ka pipe ipin 2. A. Ọba 15
Wo 2. A. Ọba 15:23 ni o tọ