2. A. Ọba 17:19 YCE

19 Juda pẹlu kò pa aṣẹ Oluwa Ọlọrun wọn mọ́, ṣugbọn nwọn rìn ninu ilana Israeli ti nwọn ṣe.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 17

Wo 2. A. Ọba 17:19 ni o tọ