2. A. Ọba 17:20 YCE

20 Oluwa si kọ̀ gbogbo iru-ọmọ Israeli silẹ, o si wahala wọn, o si fi wọn le awọn akoni lọwọ, titi o si fi ta wọn nù kuro niwaju rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 17

Wo 2. A. Ọba 17:20 ni o tọ