2. A. Ọba 17:21 YCE

21 Nitori ti o yà Israeli kuro ni idile Dafidi; nwọn si fi Jeroboamu ọmọ Nebati jọba: Jeroboamu si tì Israeli kuro lati má tọ̀ Oluwa lẹhin, o si mu wọn ṣẹ̀ ẹ̀ṣẹ nla.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 17

Wo 2. A. Ọba 17:21 ni o tọ