2. A. Ọba 17:39 YCE

39 Ṣugbọn Oluwa Ọlọrun nyin ni ẹnyin o mã bẹ̀ru; on ni yio si gbà nyin lọwọ awọn ọta nyin gbogbo.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 17

Wo 2. A. Ọba 17:39 ni o tọ