2. A. Ọba 18:35 YCE

35 Tani ninu gbogbo awọn oriṣa ilẹ wọnni ti o gbà ilẹ wọn kuro lọwọ mi, ti Oluwa yio fi gbà Jerusalemu kuro lọwọ mi?

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 18

Wo 2. A. Ọba 18:35 ni o tọ