2. A. Ọba 18:36 YCE

36 Ṣugbọn awọn enia pa ẹnu wọn mọ́, nwọn kò si da a li ohun ọ̀rọ kan: nitori aṣẹ ọba ni, pe, Ẹ máṣe da a li ohùn.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 18

Wo 2. A. Ọba 18:36 ni o tọ