2. A. Ọba 18:5 YCE

5 O gbẹkẹle Oluwa Ọlọrun Israeli; ati lẹhin rẹ̀ kò si ẹniti o dabi rẹ̀ ninu gbogbo awọn ọba Juda, bẹ̃ni ṣãju rẹ̀ kò si ẹnikan.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 18

Wo 2. A. Ọba 18:5 ni o tọ