2. A. Ọba 18:6 YCE

6 Nitoriti o faramọ Oluwa, kò si lọ kuro lẹhin rẹ̀, ṣugbọn o pa ofin rẹ̀ wọnni mọ, ti Oluwa ti pa li aṣẹ fun Mose.

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 18

Wo 2. A. Ọba 18:6 ni o tọ