2. A. Ọba 19:11 YCE

11 Kiyesi i, iwọ ti gbọ́ ohun ti awọn ọba Assiria ti ṣe si gbogbo ilẹ, ni pipa wọn run patapata: a o ha si gbà iwọ bi?

Ka pipe ipin 2. A. Ọba 19

Wo 2. A. Ọba 19:11 ni o tọ